Fight to Finish

by Fela Kuti · · Afrobeats
Lyrics Karaoke

Quick Answer — Fight to Finish Lyrics

[00:10.22] Ẹba mi wa (eh oh) [00:14.12] Ẹba mi wa wa o ehn [00:19.10] Bo s'ake ni (eh oh) [00:23.49] Ẹba mi wa wa o (ehn)
Afrobeats 1971 English

Fight to Finish Full Lyrics

Ẹba mi wa (eh oh) Ẹba mi wa wa o ehn Bo s'ake ni (eh oh) Ẹba mi wa wa o (ehn) Bo s'ebọn ni (ehn oh) Ẹba mi wa wa o (ehn ehn) Ẹgbe ke yan Ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa wa o (ehn eh o) Arinfin to gbe ko mi ti pọju Iwosi to gbe kan mi ti pọju Irẹjẹ to gbe wọ mi ti pọju Iwosi to gbe kan mi ti pọju Bo s'ake ni Ẹba mi wa wa o (ehn eh o) Ẹba mi wa (eh oh) Ẹba mi wa wa o (eh) Bo s'ake ni (eh oh) Ẹba mi wa wa o Ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa Mo gb'eke yan Ẹba mi wa, ẹba mi wa eh Ẹba mi wa (eh oh) Ẹba mi wa wa o (ehn) Ẹba mi wa (eh oh) Ẹba mi wa wa o Bo s'ake ni (eh oh) Ẹba mi wa wa o Bo s'ebọn ni (ehn oh) Ẹba mi wa wa o ehn Iwosi to gbe ko mi ti pọju Irẹjẹ to gbe ko mi ti pọju Irẹjẹ to gbe wọ mi ti pọju Arinfin to gbe ko mi ti pọju Bo s'ake ni eh oh Ẹba mi wa wa o ehn Mọ gbọ, mọ gbọ bi wọn si wi Mọ gbọ bi wọn se n sọ, mọ gbọ Mọ gbọ, mọ gbọ bi wọn si wi Mọ gbọ bi wọn se n sọ, mọ gbọ, mọ gbọ Mọ gbọ, mọ gbọ, mọ gbọ Esu lo se driver to pa mi l'aja o Esu lo se driver to pa mi l'aja Esu lo se driver to pa mi l'aja o Esu lo se driver to pa mi l'aja Aja to ti n po ya funmi o Wa ya keji kama f'ewu ya o Esu lo se driver to pa mi l'aja o Bo s'ake ni eh oh Ẹba mi wa wa o ehn Ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa wa o eh eh Ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa, ẹba mi wa Iwosi to gbe ko mi ti pọju Irẹjẹ to gbe ko mi ti pọju ah Iwosi to gbe ko mi ti pọju eh K'ẹru rẹ ko ma lọ le o K'ẹru rẹ ko ma lọ le o

Frequently Asked Questions

When was "Fight to Finish" by Fela Kuti released?

"Fight to Finish" by Fela Kuti was released in 1971.

What genre is "Fight to Finish" by Fela Kuti?

"Fight to Finish" by Fela Kuti is a Afrobeats song.

What are the opening lyrics of "Fight to Finish"?

The opening lyrics are: "[00:10.22] Ẹba mi wa (eh oh)"